Ogun asiri bibo
Ibalopo oju orun/ Alakala......
Ewe bomubomu eyo meta, odindin atare kan, aojo, aolo, aofi singbere yi ka orun wa odaju
Hajia Morenike no 8
OGUN FUN ENI TOHUN NI IBALOPO OJU ORUN ATI ALAKALA....
Ako Alangba, Eyin adie kan aofitele ape aoko, Ewe sasamura lelori a o se lagbo, ti obajina aoko ewe na sile aoduro lelori aowe agbo naa, aowaje Eyin adie yen nibe, atisegun ibalopo oju orun ati alakala niyen..
ALA WIPE OKUNRIN NI IBALOPO LOJU OORUN( Ifasehin ni Awon Aye ma n fi eyi se fun eniyan)
E lo wa osun abalaye ki e loo ni ileele pelu eyo ataare meta ki e fi sin oke inkan omokunrin yin si oke ki o je meta pere, eo ji laaro kutu ja ewe ewuro ki oorun to yo yio je 201, ao gbo 200 sinu omi ao gbe si oorun laaro ao da eyo ataare 7 si ao fi owo meta daa bi agbelebu, ao fi sibe, ao gun eyokan ti o ku mose ti e le fi we leekannaaa ao se(sieve) omi yen n ao gbe omi yen ao lo fi we ose yen ni ale ki a to lo sun. Pelu ase Olohun gbogbo ona ti won ba di mon wa yo si patapata
OSE ASINA
Ewe Akoko toojo 21, eyi ti ko lu rara . A o fi rori sun moju, ti ile ba ti mo dada A o lo po mo taba mimu, A o po mose eyikeyi. A o ma fi we
ITUWO AWON AGBALAGBA
A o gun epo obo mose, A o fi epo pupa po ose naa. A o ko sinu fitila oloju kan, A o ma fi ose naa we ni gbogbo igba
AJEGUN
Egbo lapalapa ati odidi atare ao jopapo ao lo ao ma fi epo pupu la ninu awo ipese
ASEJE OWO
ewe abamoda kan ewe ogbo kan aolo pelu ata ijosi aofise igbin ilako kan je lepo niyo
AWEBI WEPE DANU
Ao lo wa epo obo die ao gun mo ose dudu pelu ewe bomubomu ao lo fi we lodo lekan soso.
BASIRI Mi
Afatan irun ori wa, AO fi bo agbado odindi kan ti omo inu re ko din rara. AO lo rimole ao ma Fi omi fo ori wa si ori ile agbada yi titi yio fi hu sita bi ika owo wa. Ao wa fatu ao gbon gbogbo iyepe idire, ao Jo ao ma Fi foko mu
IPARA ANU
ao wa ewe anu gbigbe,ao lo pelu kafura pelebe,ao lo papo,ao da sinu ipara.... Ao mo fi para
ISE ANU
A o fi oti gbo ewe orijin ati ajeobale a tu milk si odi mimu....
AWORO
ori ako ati abo alangba aojomo odidi atare kan aofi iyo die si aoro sinu ato aosoko inu ile abi shop.aonide lenu
OSHOLE TODAJU
Ori eye osin kon, odidi igbin toba gbonu kan, ewe omisimisi gogoro, ewe ogo, aojopo aolo kunna daada aoma firo ekuru fun fun je laarin oru.
AKO EYONU AWON AJE TI WON YIO FI SEWA LORE
. eye kowe dudu kan eye konakona ti won kola inu re, odidi ejo paramole kan, eye alapandede kan, igbin bonu kan, ogede omimi meji, ewe omisimisi oloju ologbo ao jo gbogbo re papo ao ro sinu sere ao wa pa akuko adie kan fibo sere naa ao le iye igbaya re mo lara ao mafi foko tutu mu ni moday wesday thusday awon aje yio feran wa won yio si matari aje siwa odaju
Ogun Okiki
Akere Tope, Akuko adie kan, Eye Owiwi 1 ,ori Akuko Ati Ori Owiwi , Ati Akere Ni Ao Lopo Tiyio Kunna Dada Ao Pomo Ose Dudu , Ao Mafiwe Mawi Mawi Nise Eye Owiwi, Owiwi Loni Ki Won Mawimin Kaye Aniyan, Toripe Akere Nijuwe Ibiti Odo Wa Aniyan, Akuko Nijuwe Ilu Ki Omoaraye Majuwe Mi Si Dada , Odiwiwe .
: ISE APASE PAKATI TODAJU.
Ori oka to lase lenu kan, Orogbo ori sango, odidi state kan. A o ji papo, A o po lose dudu, A o pin ose naa si ona meji, A o pin si inu Iwo Igala meji ni kan kan. A o ma fi okan se Adura, A o ma fi okan sepe.
A o fi aso funfun we ti aladura, A o fi aso pupa we ti elepe. A o se aamin(Mark) si. A o ma tola.
Agbara la ko wa, ka to ma wa oro, owo, ola.
Abo oro to fun omoluwabi eniyan.
Eniyan to lowo ti ko ni agbara, asan lo gbe lowo.
Sugbon Oga ni alagbara yii ma je fun olowo, oloro...
Nitoripe Alagbara le fi agbara gba ohun gbogbo tolowo toloro gbojule ni ojo kan soso.
*IPESE ASINA AWON AJE*
ori okete kan ao jo pelu odidi atare kan, Lilire ao tu eko elewe kan, ao tu ao fi nu gbogbo ara wa pelu adura, ao so eko na sinu awosobi ao da etu ti ajo yen si yio bo ara eko na dada,ao bu epo si, ao fi obi abata oloju merin kan bere boya epo na to, ao tun fi bere boya igorita logba tabi ori akitan, ihoho ni ao wa ti aba fe se adura si o. *A ku imunsile ipade wa yiooooo*
Awure todaju...eku eda ogiri ijebu,aso etu,ao gun gbogbo re papo ao po lose ao mafiwe ofore....akitan maja legba3*orangun maja lofa3*aki binu omo osu lole,eyin ni iyami osoronga,akii bayin yahun kase yin,akii bayin yahun ki oju owo pon ni,aki bayin yahun ki oju omo pon ni,eku eda ko lo dari iree temi wa bami,ogiri ki o lo dari aje temi wa bami girigiri,etu ki o lo ture temi jo funmi wa,ao ma pe ofore si ao mafiwe nigba ti aba ti nwe odaju ogun aiye atijo ni
BIBO ASIRI BOYA ANI BUKATA TI AFE BIYA TABI ANI INAWO ALANU AWA WARI
amaja odo ewe lapa ff,odo ewuro pelu iyere ati ewe ola die,alo papo afi din eyin agirck meta,pelu epo pupa ati iyo ase adua si awaje odaju
Oshole:- ewe oriji, ewe sekirimidin, ewe akoko, Ori eye osin, ori owawa, ori agbe, ori Aluko, ori odidere, ewe gbegbe, ewe Rere ao gun mose pelu eje eyele kan, ao wa ra eyele mi ao ge Ori e so fi tele igba ao wa ko ose na lelori. Ojo keta ni ao ma fiwe.
SETA:- ako alangba kan, epo obo, odidi atare kan jo po a po lose a ko sinu Awo sobi a ma fi ose na we.
OGUN TA FI NGBALE:- eso las pupa, ori ologbo ehana kan, jo a ro sinu Igo funfun kan ,
LILO RE:- ao by ninu eyu yi sinu efe owu awe in kobere, a wa Lori sor ile na
OHNU RE:-ENIKENI TO BABA WA DU ILE YI KI OLOGBO MAMA BAMI BU WON JE.
ASHIRI BIBO:- ewe Aje, eja abori nla, igbin nla kan, eyin adie ororo kan, iru woro, ata ijosi 9 so se laseje lepo ni yo,ti obe na bati fe jina ao fo eyin yen si lori ina,
JEJERE:- a fi iyerosun te ifa ejiogbe.
Ofore:- wnikan ki mo ohun ti sefusefu fi nse Owo 3* enikan ko mo ibi ti adie nkodi si yi fi nyeyin 3* abotan lorisa oke nbo digbin3* nise ni ki asiri Emi lol ma bo fowo NLA nla,, tokunein tobinrin ki Omo araye Mase rodi Emi lol laye o.ao da so be na w a je. Emi na ni Woli Opa 07017377911
Thank u
ReplyDeleteAma ju yin see ooo lagbara eledua
ReplyDelete