Ogun iferan
*Nitori Awon Baba Wa Kan Ati Awon Iyawa Ninu Ile Yi To Wan Ni Idojuko Ninu Ile Won E Je Ki Nfi Awon Ise Yi Ran Wa Lowo* *(AFUNJE OBINRIN TODAJU)* HUMMM AWON OBINRIN ROGO NI OWO AWON OKUNRINN BAYI OOO OBINRIN TI OTI SO ARARE DI OLOHUN EBAMI FUNI ISEYI JE;- ao wa ewe abaluku eyokan toba tobi dada (iyalode funfun) ao te ewe na si ilele ao wa ya igbe le lori taba ya tan ao wayo okun sokoto idi wa ao ka ao mafi nu igbe na ni otun atosi pelu ofore leyina ao wa yo ewe na ni abe igbe yen ao fisinu isasun pelu okun sokoto yen ati odidi atare kan ao jopo ao fun obinrin na je.
(OFORE) ewe abaluku kifi ilu sile oni kakaki on yafi ilu sile ohun yoya ba ilu ku ni, okun sokoto kiya idi, ibiti aba su igbe si ibe na ni ito raasi ki lgbaja male fimisile gbogbo igba ni ki L omo L mafi nife emi L omo L. Adua.
*(AFUNJE OKUNRIN TODAJU)* HUMMM EYIN OKUNRIN TI EYINA O RANTI IYAWO ILE NA MON ETI ROGO LOWO AWON OBINRIN BAYI OOO KOSI IYANJE MON:- eyin obirin elo bami wa eran naman ekiri kan kie wafi eran na si oju arayin lati ago mefa irole 6pm di idaji ojo keji toba di ago mefa aro 6am ojo keji kie wa yo eran na kie fisinu isasun kie fi odidi atare kan si legbe kie wa ko ewe reku reku bo monle odi jijo tie ba jo tan kie lo kokuna dada kie ma fisinu ounje baale yin haaa kotun wo ibomiran man laye odaju pupo. *A ku imunra sile fun ipade wa yiooooo*
Imule to daju
Eye kowe dudu kan isu esuru pupa ati atare kan ,ao fi kowe dudu tele ape ao ko esuru lelori ao fi atare si o di jijo papo
Lilo re; aofi oti Lo laro aofi epo pupa lo lale. Tested and confirmed, aje funwa o
AFUNILOWO TABI AWURE
AWO OJU ILU BEMBE, EPO IGI ABA ELEWE NLA, AO LO WON PO EJA ARO TUTU ( CATFISH) , LAO FISEJE,
OMO-ORUNMOLA . 53
ASINA
EKU ASIN KAN OPOLO GBIGBE KAN EPO OBO EWURO ATARE ODINDIN KAN AOJO PO AI MA FI LO OYIN NI AGO KAN ORU.
BY ME AGBARA OMI
OSOLE ARISIKI
EWE ABAMODA 201,EWE ALUPAIDA 201 ODINDIN ATARE KAN AO JO PO AO DA SINU OYIN AO MA LA ODAJU
BY ME AGBARA OMI
ASIRI BIBO
ORI OLONGBO TONI IRUN ESO LARA PUPA ATI FUNFUN PELU ODINDIN ATARE KAN AO JO PO AO MA FI MILK LO TABI OTI
ASINA TODUju
ALANGBA AKO PA,PELU IGI TI AFI PA ,OJU OLONGBO ODINDIN ATARE KAN AO MA FI OMI TABI OTI LO LARO.
BY ME AGBARA OMI
Edan Aje:- ewe odunkun,ewe awede, ewe sekinimidin, ewe ESO,ewe sawerepepe, mariwo Ope, tete abalaye, efo gure, so rate edan meji, ako ati abo, so pa Gbogbo ewe yen po ninu ike funfun NLA kan ao wa da omi agbon topo le lori Pelu oti dry gin, ao wa ko edan mejeji si, ao ma fi omi yi we fun ojo meta, ni ojoketa tati we tan a ko edan na sori nkan kogbodo kanle ao wa fi eyele funfun Pelu eyetu bo awon edan na ao wa ko sinu Awo fun, ao ma fi ekuru se Sara fun edan yi ao si ma fi dry gin si ni gbakugba taba feran nise Pelu Adura, Edan Alaje ni. Osohole:- Ori oka tolase leun kan, Awo lili totobi kan, odidi atere kan, Owo tuntun totobi (#1000) a fa irun Ori lafatan ao fi Owo tele inu Awo lili na, Ori oka tele, atare loke a fi irun yen bo ao Jo a lokunna ao ma fi oti schnnap to gbona loo odaju. Ekaro Gbogbo ile emi Omo yin ni Woli Opa mo npada bo.
Fun ita tabi igbona, E lo wa ewe rinrin ki e lo loju olo, e pin so ona meji . efi ekinni se aseje lepo niyo,. On a keji,efi epo pupa die si, kie fi pa onitohun lara. Ki ama se fi pa atelewo pelu atelese. Logo Olorun ara onitohun yio bale.
Mosi tun she ebu oshole yi.
A o wa eso bomubomu a o la tenre a oki N200, tuntun ti a ka ti aworan eniyan inue koju si ita, pelu odidi atare kan bo inue ti koni han sita rara, a o wa jo, a o lo kuna, a o fi oti loo ni aro kutukuti ki ato ba enikankan soro, ni ihoho omo luabi. A o se adura ohun ti a fe si kato loo.
ELEYI WA FUN OLORIN TOFE KORIN AKO-GBAYI LODE ORIN🎤🎼
(OGUN OLORIN TODAJU )
Eiye AWOKO, atare, sekere
aloku ti koba si ileke larare
mo, ao ha arare ao wa gun
po mo atare naa ao wa yo
okan eye AWOKO naa ao tun
gun po mon oun ti ati gun
naa yio Dabi agunmu ao ma
fi oti oyinbo loo fun ojo
mesan sugbon ti aba fe losi
ibi Orin ao tun loo lo enina ma korin tio kori
yio korin akogbayi, awon aye o siwona fun oooo
By Me Akeem Moshood IKUOGBOOGUN
Aseje owo
Ewe abamoda 3, pelu ata ijosi 9, a lo lori olo and fi po eyin agric 3, a wa da sinu nilonu ti won fi di sugar ao fi iyo die si, ao se jina, a o wa se adura si ki a to je. Odaju
Ose
Get ewe iyalode funfun ati pupa 3 ,3 ti ko luju, a o lo pelu koun bilala die kan, a o wa lo lori olo a o wa fi ose ko, ti o ba di ni ale ao wa eki elewe a wa ge si meji, a o mu ti ori yen a o fi epo po ninu abo laifi omi si, a wa fi pa gbogbo ara lati ori, a o wa we ose na pelu kankan tutun. Ao wa losun lale ojo na lai jade sita mon
Ogun iferan todaju
Ota inun iroko,epo egusi ti obinrin se funra re,ao lo papo ao da sinu bintle ao ma fi para lo ba obinrin naa.
Ewe a ma je ooo
ReplyDeleteEwe ama me oo
ReplyDelete