Ogun

Irun ori oku. Ewe alupaida tutu. Panumo abo. Panumo abafe. Ati bombom.  Alapa ile. Ao Jo pelu atare kan. AO dini owu dudu ati

Oforee
Panu abo ki n ba abo wijoo. Panu abafe ki ba abafe fo ohun.  Awufo ohun ni ti bombom. Alanu fo ohun ni ti alapa. Oku ti oti ku ki ba ara ayee wijoo.
                        ( 2)
Irun ori odi. Panu abo. Ati panu mo abafe. Ewe alupaida tutu. Owo eyo ti ko luju. Ao fi ba obinrin sun. Ihoho lama JA awon ewe yen ao wa Jo pelu atare odidi kan ao o dini owu funfun ati dudu.

Oforee
Panu mo Kiri enu roojoo. Panu mo abafe ki ba abafe fo ohun odi kiri enu ati soro. Gbogbo ise ti oko ba see ida obo ni gba

Comments

Popular posts from this blog

Ogun iferan

Ogun asiri bibo

Aseje owo 50'000