Oshole ati aworo
*OSOLE AWURE*
eiye kannakana kan tope daada,oga meta to pe dada, odidi atare meta, ao gbe ape tuntun kan ka ori ina,ao da epo pupa igo kan,adin igo kan,oori to tobi abokan ao gba lori ina,ao gbe eiye yen ju si, a gbogbo eroja yioku ao jo papo,ao lo kuna daada ,ogere epo lale eko gbigbona laaro
gbogbo ile e je Kalo dan ise yi wooo
*By : - no 01 woli adejorin michael a k a iyamah iyamah*
*AWURE TI OWO KOFI NIDA LOWO*
eiye kowe dudu meta,ajeku ireke tiwon je soja,ooyo oko ti a loja funrawa,ewe omoonigelegele lopolopo,odidi atare kan ao ko eiye meteta tele ape ao da ajeku ireke yi sii ao fi odidi atare kan si ao wa da ewe omoonigelegele yen bo mole ,odi jijo ao lo papo ao da sinu ike funfun kan,ao tu peak milk meta si otin igo meta,ao wa ju eiye koowe dudu miran ao ju sinu ike yen ao ma mu ni aro kutu lai fohun si eniyan, haaaa ise ni danwo
*By : -no 01 woli adejorin michael a k a iyamah iyamah*
Aworo
_Isasun agbebi kan to she die ao ju opolo elede si inu re ao ko ewe omisinmins pelebe si lori ao wa da oyin ilaji igo si lori ao fi omo ri re depa ao wa di isasun na ni owu dd ati ff ao wa ri mo enu ona ofice wa pelu ogo lodo olohun aworo tin shishe ni_
**By humar faruq owo lafin wowo*41*
_Ejeee kalo wa aje idi ore epo jebo ao gun mejeji yi po mo ata ijosi mesan ao ge edo malu si mesan_ao se lepo ati iyo ao koje ni gbogbo na be_
_Aseje yi ma mu owo gidi wa ti eyan bani eyonu gidi lara_
*From ✍🏿✍🏿✍✍✍alfa humar faruq* **owo lafin wowo*41*
2019 ford fusion hybrid titanium - iTanium-arts.com
ReplyDelete2019 ford revlon titanium max edition fusion fusion fusion titanium. The titanium oxide layer is made of iron camillus titanium oxide and titanium daith jewelry provides a titanium white fennec strong, stable surface titanium drill bits for metal with a strong