Posts

Showing posts from September, 2018

Ogun

Irun ori oku. Ewe alupaida tutu. Panumo abo. Panumo abafe. Ati bombom.  Alapa ile. Ao Jo pelu atare kan. AO dini owu dudu ati Oforee Panu abo ki n ba abo wijoo. Panu abafe ki ba abafe fo ohun.  Awufo ohun ni ti bombom. Alanu fo ohun ni ti alapa. Oku ti oti ku ki ba ara ayee wijoo.                         ( 2) Irun ori odi. Panu abo. Ati panu mo abafe. Ewe alupaida tutu. Owo eyo ti ko luju. Ao fi ba obinrin sun. Ihoho lama JA awon ewe yen ao wa Jo pelu atare odidi kan ao o dini owu funfun ati dudu. Oforee Panu mo Kiri enu roojoo. Panu mo abafe ki ba abafe fo ohun odi kiri enu ati soro. Gbogbo ise ti oko ba see ida obo ni gba

Oshole ati aworo

*OSOLE AWURE* eiye kannakana kan tope daada,oga meta to pe dada, odidi atare meta, ao gbe ape tuntun kan ka ori ina,ao da epo pupa  igo kan,adin igo kan,oori to tobi abokan ao gba lori ina,ao gbe eiye yen ju si, a gbogbo eroja yioku ao jo papo,ao lo kuna daada ,ogere epo lale eko gbigbona laaro   gbogbo ile e je Kalo dan ise yi wooo *By : - no 01 woli adejorin michael a k a iyamah iyamah* *AWURE TI OWO KOFI NIDA LOWO* eiye kowe dudu meta,ajeku ireke tiwon je soja,ooyo oko ti a loja funrawa,ewe omoonigelegele lopolopo,odidi atare kan ao ko eiye meteta tele ape ao da ajeku ireke yi sii ao fi odidi atare kan si ao wa da ewe omoonigelegele yen bo mole ,odi jijo ao lo papo ao da sinu ike funfun kan,ao tu peak milk meta si otin igo meta,ao wa ju eiye koowe dudu miran ao ju sinu ike yen ao ma mu ni aro kutu lai fohun si eniyan, haaaa ise ni danwo *By : -no 01 woli adejorin michael a k a iyamah iyamah* Aworo _Isasun agbebi kan to she die ao ju opolo elede si inu re ao ko ewe ...

Aseje owo 50'000

Aseje owo(Pepper soup 4 money)#50,000 upwards Ewe lapalapa funfun (Jatropha curcas) mejila aoko mefa tele aoko eyin agric 3 le ao wafi mefa yoku bo ao se jina laisi omin ao daniyan owo si niti bukata tanfe ao waje.  Koda ogbe #200,000.  Kabuki shinobi🈚🈷🈶🈸 Gbogbo ile ise ti baba kan fi sile ninu ile yi,ise iferan si obinrin ni o,odaju gan ni o,moti se wo,o sise gan IFERAN Ota inu iroko,epo egusi ti obinrin se,ao lo papo mon ara won,ao da sinu bintle,ao mafi pa ara lo ba obinrin na,odaju yio gbafun wa,moti sise yi,odaju.baba tofi ise yi sile,opolo yin koni daru ooo. Ashiri bibo fun inawo:- ewe bombom meji a fi Ori pa oju ewe na, a wa fi #1000 si alemo   a wa fi ewe kan toku bo Owo yi a wa Latin ewe mejeji, a jo pelu odidi atare kan, a lo ao fi hot lo tan lekan soso. E kale Gbogbo ile, a ku ipale mo a ba wa layo. OSE AWURE NI. Ewe owu akese, ewe ajeobale, ewe laali, aogun po mo ose, ao ma fiwe ni aroo... iba eyin agbagba EYONU. ...

Ogun iferan

*Nitori Awon Baba Wa Kan Ati Awon Iyawa Ninu Ile Yi To Wan Ni Idojuko Ninu Ile Won E Je Ki Nfi Awon Ise Yi Ran Wa Lowo*   *(AFUNJE OBINRIN TODAJU)* HUMMM AWON OBINRIN ROGO NI OWO AWON OKUNRINN BAYI OOO OBINRIN TI OTI SO ARARE DI OLOHUN EBAMI FUNI ISEYI JE;- ao wa ewe abaluku eyokan toba tobi dada (iyalode funfun) ao te ewe na si ilele ao wa ya igbe le lori taba ya tan ao wayo okun sokoto idi wa ao ka ao mafi nu igbe na ni otun atosi pelu ofore leyina ao wa yo ewe na ni abe igbe yen ao fisinu isasun pelu okun sokoto yen ati odidi atare kan ao jopo ao fun obinrin na je. (OFORE) ewe abaluku kifi ilu sile oni kakaki on yafi ilu sile ohun yoya ba ilu ku ni, okun sokoto kiya idi, ibiti aba su igbe si  ibe na ni ito raasi ki lgbaja male fimisile gbogbo igba ni ki L omo L mafi nife emi L omo L. Adua. *(AFUNJE OKUNRIN TODAJU)* HUMMM EYIN OKUNRIN TI EYINA O RANTI IYAWO ILE NA MON ETI ROGO LOWO AWON OBINRIN BAYI OOO KOSI IYANJE MON:- eyin obirin elo bami wa eran naman ekiri kan ki...

Ogun asiri bibo

Ibalopo oju orun/ Alakala...... Ewe bomubomu eyo meta, odindin atare kan, aojo, aolo, aofi singbere yi ka orun wa odaju Hajia Morenike  no 8 OGUN FUN ENI TOHUN NI IBALOPO OJU ORUN ATI ALAKALA.... Ako Alangba, Eyin adie kan aofitele ape aoko, Ewe sasamura lelori a o se lagbo, ti obajina aoko ewe na sile aoduro lelori aowe agbo naa, aowaje Eyin adie yen nibe, atisegun ibalopo oju orun ati alakala niyen.. ALA WIPE OKUNRIN NI IBALOPO LOJU OORUN( Ifasehin ni Awon Aye ma n fi eyi se fun eniyan) E lo wa osun abalaye ki e loo ni ileele pelu eyo ataare meta ki e fi sin oke inkan omokunrin yin si oke ki o je meta pere, eo ji laaro kutu ja ewe ewuro ki oorun to yo yio je 201, ao gbo 200 sinu omi ao gbe si oorun laaro ao da eyo ataare 7 si ao fi owo meta daa bi agbelebu, ao fi sibe, ao gun eyokan ti o ku mose ti e le fi we leekannaaa ao se(sieve) omi yen n ao gbe omi yen ao lo fi we ose yen ni ale ki a to lo sun. Pelu ase Olohun gbogbo ona ti won ba di mon wa yo si patapata OSE ASINA E...